Kòfowórayọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Kòfowórayọ̀

He/she didn't use money to buy happiness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kò-fi-owó-ra-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kò - he/she/it didn't
fi - use
owó - money
ra - buy
ayọ̀ - joy, happiness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS