Kòfowórọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Kòfowórọlá
This wealth isn't bought. She did not buy this wealth with money.
Àwọn àlàyé mìíràn
The name means the child either was born wealthy or inherited wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
kò-fi-owó-ra-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kò - (he/she) didn'tfi - use
owó - money
rà - buy
ọlá - wealth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Kòfowórọlá Bucknor
deputy Governor of Lagos State 1999-2002.