Kìkìirelolúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Kìkìirelolúwa
God is pure goodness. God is all good.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
kìkì-ire-ni-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kìkì - filled with, completelyire - goodness
ni - is
olúwa - lord, God
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS