Karóunwí

Sísọ síta



Ìtumọọ Karóunwí

Another way of writing "Károhunwí": That we may find something to say.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kí-á-rí-oun-wí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kí - that
- we
rí - see
oun - something
wí - say


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN