Kalẹ̀jaiyé
Sísọ síta
Ìtumọọ Kalẹ̀jaiyé
Sit down to enjoy life.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ka-ilẹ̀-jẹ-ayé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kà - touch, put onilẹ̀ - ground
kalẹ̀ - sit down
jẹ - enjoy
ayé - life
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA