Kásìmawò
Sísọ síta
Ìtumọọ Kásìmawò
Let's continue to observe him/her.
Àwọn àlàyé mìíràn
The tonal variation on the last vowel insists that we write it as "Kásìmawòó". It is an àbíkú-themed name for children not usually expected to grow into adulthood.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
kí-á-sì-máa-wòó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kí - thatá - we
sì - yet
máa - continue to
wòó - look at him/her, observe him/her
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA