Kányinsádé
Sísọ síta
Ìtumọọ Kányinsádé
Adding sweetness to royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
kán-oyin-sí-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kán - add a drop ofoyin - honey
sí - into
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
GENERAL