Kányinsọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Kányinsọ́lá

Make wealth have more savour. Add a taste of sweetness to wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kán-oyin-sí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kán - to put a drop
oyin - honey, sweetness
sí - into
ọlá - wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kányin

Kóyinsọ́lá

Kóyin

Kọ́nyinsọ́lá