Káṣìmáawòó
Sísọ síta
Ìtumọọ Káṣìmáawòó
Let's continue to observe (him/her).
Àwọn àlàyé mìíràn
This is an àbíkú name, given to a child believed to be prone to dying only to return again in the future.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
kí-á-ṣì-máa-wòó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kí - letá - us
ṣì - still
máa - continue to
wòó - watch/observe (him/her)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA