Kàyíkúnmi
Sísọ síta
Ìtumọọ Kàyíkúnmi
Count me worthy of this one (child).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ka-èyí-kún-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ka - to consider, to respectèyí - this (one)
kún - in addition to, fulfillment
mi - me, mine
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL