Kúyọ̀ọ́ró
Sísọ síta
Ìtumọọ Kúyọ̀ọ́ró
Death spared (him/her).
Àwọn àlàyé mìíràn
It's an "abiku" name.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ikú-yọ̀-ọ́-ró
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ikú - deathyọ̀ - spare
ọ́ - him/her
ró - stand (dúró)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
