Kúpàyí

Sísọ síta



Ìtumọọ Kúpàyí

Death did not killed this one.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ù-pà-èyí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
pa - kill
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL