Kúgbàyígbé

Sísọ síta



Ìtumọọ Kúgbàyígbé

A shortened form of Ikúgbàyígbé, Death has forgotten this (child).



Àwọn àlàyé mìíràn

Founder of the town Òkè-Igbó in Oǹdó state. See Kúgbàgbé.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-gbà...gbé-èyí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
gbà...gbé - forget
èyí - this


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Ikúgbàyígbé