Kúṣìmọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Kúṣìmọ̀

Death could not recognize (the child).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ṣì-mọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
ṣì - to mistake
mọ̀ - know


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Ikúṣìmọ̀

Ikúṣìmímọ̀

Kúṣìmímọ̀