Kùtùọláyẹni

Sísọ síta



Ìtumọọ Kùtùọláyẹni

The early arrival of honor/wealth befits a person.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kùtù-ọlá-yẹ-ẹni



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kùtù - early morning
ọlá - honour, wealth, success, notability
yẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
ẹni - person


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Ọláyẹni