Kòṣééfọ́wọ́kàn
Sísọ síta
Ìtumọọ Kòṣééfọ́wọ́kàn
(This child) cannot be maltreated (because he/she is protected by Èṣù)
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
kò-ṣeé-fi-ọwọ́-kàn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kò - [negation]ṣeé - capable of
fi - use (it)
ọwọ́ - hands
kàn - touch, reach
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL