Kíyèsẹ́ní

Sísọ síta



Ìtumọọ Kíyèsẹ́ní

Be mindful of the mat.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is a name given to a child whose size at the early stages is very small. The name is a reference to others walking by the mat to be careful not to step on the baby because of its size.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kíyèsí-ẹní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kiyèsí - be aware of, be careful about, pay attention to
ẹní - mat


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EFON