Kékeréogun

Sísọ síta



Ìtumọọ Kékeréogun

Young warrior.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Kékeré Ẹkùn



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kékeré-ogun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kékeré - small, young
ogun - war


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL