Jógunómí

Sísọ síta



Ìtumọọ Jógunómí

Let the war be.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is the name of a famous Yorùbá warrior.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ́-ogun-ó-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ́ - let
ogun - war
- [particle]
mí - breathe, be


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Jógunómín