Jíbádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Jíbádé

Wake up to the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jí-bá-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jí - wake up, rise
bá - meet
adé - crown


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Ajíbádé.