Jésùpémi
Sísọ síta
Ìtumọọ Jésùpémi
Serving Jesus profits me.
Àwọn àlàyé mìíràn
Clearly a Christian name, and most likely a recent adaptation of earlier names like Ọ̀súnpémi, Ifápémi, etc.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
jésù-pé-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
jésù - Jesuspé - profits, pays
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE