Jayéìfẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Jayéìfẹ́

Enjoy a world of love.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ-ayé-ìfẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ - enjoying
ayé - life, world, earth
ìfẹ́ - love


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Jaiyéìfẹ́

Jaiyé

Jayé