Jaiyéìfẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Jaiyéìfẹ́

Enjoy a life of love.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ-ayé-ìfẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ - eat, enjoy
ayé - life, earth, world
ìfẹ́ - love


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Jayéìfẹ́

Jayé

Jaiyé