Jákàndè
Sísọ síta
Ìtumọọ Jákàndè
(One who) frees the sacrificial animal for the babaláwo.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
já-ìkàn-ní-ìdè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
já - cut, set looseikàn - a sacrificial animal
ní - [particle]
ìdè - bondage
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Lateef Jákàńdè
former Governor of Lagos.