Jọláoshó

Sísọ síta



Ìtumọọ Jọláoshó

Enjoy the riches of a sorcerer.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ-ọlá-oṣó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ - enjoy, eat
ọlá - wealth
oṣó - sorcerer, òrìṣà oko


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
GENERAL



Irúurú

Jọláoṣó