Jọláolú

Sísọ síta



Ìtumọọ Jọláolú

One who benefits from the wealth of the lord.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Jọláadé



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ-ọlá-olú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ - benefit from, eat
ọlá - wealth, nobility
olú - lord, prominent one, hero


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Jọlá