Jẹ́nrọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Jẹ́nrọ́lá

Permit me to see/find wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ́-(kí)-n-rí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ́ - let
n - me (mi)
rí - see, find
ọlá - wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS