Jẹ́nrẹ́yìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Jẹ́nrẹ́yìn

Allow me to see my future.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ́-kí-n-rí-ẹ̀yìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ́ - let
kí - that
n - me (mi)
rí - see, find
ẹ̀yìn - future


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL