Jẹ́ngbésì

Pronunciation



Meaning of Jẹ́ngbésì

See: Fájẹ́ngbésì (Ifá sends me a response).



Extended Meaning

See also: Olújẹ́ngbésì, Adéjẹ́ngbésì, etc



Morphology

jé-n-gbọ́-èsì



Gloss

- let
n - me (mi)
gbọ́ - listen to, attend
èsì - answer, response


Geolocation

Common in:
ONDO



Variants

Fájẹ́mgbésì

Fájẹ́ngbésì

Ifájẹ́ngbésì

Ifájẹ́migbésì

Jẹ́migbésì

Jẹ́mgbésì