Jẹ́misìgbìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Jẹ́misìgbìn
Let me worship the Ìgbìn.
Àwọn àlàyé mìíràn
The ìgbìn is a type of drum used by the worshipers of Ọbàtálá.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
jẹ́-mi-sìn-ìgbín
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
jẹ́ - letmi - me
sìn - worship
ìgbín - a type of drum used by Ọbàtálá worshippers
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI