Jẹ́midúpẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Jẹ́midúpẹ́

Let me be grateful.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ́-mi-dúpẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ́ - permit, to exist, to be effective
mi - me
dúpẹ́ - be thankful


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL