Jókótífá

Sísọ síta



Ìtumọọ Jókótífá

Sit with Ifa.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Dúrótifá, Rótifá



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jókòó-ti-ifá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jókòó - sit (down)
ti - with
ifá - Ifá divination


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IFE