Jésùtófúnmi
Sísọ síta
Ìtumọọ Jésùtófúnmi
Jesus is enough for me.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is a modern Christian variation of Olútófúnmi, Adétófúnmi, etc.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
jésù-tó-fún-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
jésù - Jesustó - suffice for, enough for
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN