Jésùlayọ̀mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Jésùlayọ̀mi

Jesus is my joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jésù-ni-ayọ̀-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jésù - Jesus
ni - is
ayọ̀ - joy
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Layọ̀mi