Iyùnlọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Iyùnlọlá

This child of nobility is as precious as the iyùn ornament.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

iyùn-ni-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

iyùn - Iyùn, an ornamented bead
ni - is
ọlá - nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Lọlá