Iyìolúwadémiládé
Sísọ síta
Ìtumọọ Iyìolúwadémiládé
The honour of God has crowned me (with the birth of my son).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
iyì-olúwa-dé-mi-ní-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
iyì - honourolúwa - lord, God
dé...ládé - crown
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL