Irúnṣèwé

Sísọ síta



Ìtumọọ Irúnṣèwé

See Rúnṣèwé.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is an àbíkú name given to Ìjẹ̀bú children.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

rún-ṣe-wèé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

rún - nothing (Ìjẹ̀bú dialect)
ṣe - make, create, do
wèé - him, her, it, this one (ìwé, èyí)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Rúnṣèwé