Irégbàmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Irégbàmí

Goodness saved me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ire-gbà-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ire - goodness
gbà - take, collect, receive, save
- me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Gbàmí