Irébámidélé

Sísọ síta



Ìtumọọ Irébámidélé

Goodness came home with me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ire-bá-mi-dé-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ire - goodness
- together with
mi - me
- arrive, return
ilé - home, house


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Bámidélé