Ikúlóògùn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ikúlóògùn

Death has a remedy/prevention/antidote.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ní-òògùn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
ní - have
òògùn - remedy, prevention, antidote, drugs


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI