Ikújíminọ́nẹ
Sísọ síta
Ìtumọọ Ikújíminọ́nẹ
Death does not allow me to have relatives.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ikú-ò-jí-mi-ní-ọnẹ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ikú - deathò - is not, does not
jí - to allow, permit, exist (jẹ́)
mi - me
ní - to have, own
ọnẹ - person (ẹni)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILAJE