Ikúpolókun

Sísọ síta



Ìtumọọ Ikúpolókun

Death did not kill Olókun.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ù-pa-olókun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
ù - does not
pa - kill
olókun - androgynous deity of the ocean, fertility, and wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Kúpolókun