Ikúgbọ̀nmírè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ikúgbọ̀nmírè

Death has ignored me; Death, leave me be.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-gbọ̀n...rè-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
gbọ̀n...rè - ignore, deprive, to leave
- me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Kúgbọ̀nmírè

Gbọ̀nmírè