Ikúṣebíàlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ikúṣebíàlá

Death resembles a dream.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ṣe-bí-àlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
ṣe - make, create, do; to act like
- to give birth to
àlá - dreams


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN