Ikúṣìyímọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ikúṣìyímọ̀
Death failed to identify him.
Àwọn àlàyé mìíràn
An àbíkú name.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
i-kú-ṣì-èyí-mọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ikú - deathṣì - made a mistake
èyí - this (one/child)
mọ̀ - know, identify
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL