Ikúṣìmímọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ikúṣìmímọ̀

Death failed to recognize me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ṣì-mí-mọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
ṣì - to mistake
- me
mọ̀ - know


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kúṣìmímọ̀

Ikúṣìmọ̀

Kúṣìmọ̀