Ikúèmẹnísàn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ikúèmẹnísàn
Variation of Ikúèmọnísàn, Death does not know who is good.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ikú-è-mọ-ẹni-sàn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ikú - deathè - did not
mọ - know
ẹni - someone
sàn - to be good
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILAJE