Ikúèmẹ́hìnlọ
Sísọ síta
Ìtumọọ Ikúèmẹ́hìnlọ
Death has not taken away our legacy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ikú-è-mú-ẹ̀hìn-lọ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ikú - deathè - did not
mú - to use; to hold (onto); to make, to bring
ẹ̀hìn - back, behind, legacy
lọ - to go
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO