Ifárónbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifárónbí

Ifá has found someone (good) to birth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-rí-oun-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

Ifá - Ifá divination, corpus, priesthood
rí - see, find
oun - something, someone
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Yẹmí Fárónbí



Irúurú

Fárónbí

Fáróunbí

Ifáróunbí