Ifáríbidó
Sísọ síta
Ìtumọọ Ifáríbidó
Ifá has found a place to stay/settle.
Àwọn àlàyé mìíràn
See Okùribidó, Olúríbidó.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-rí-ibi-dó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination/corpus/priesthoodrí - see, find
ibi - place
dó - found, stay at, land on, settle in, live in
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL